Sheikh kabiru gombe biography of william
Sheikh kabiru gombe biography of william hurt.
Sheikh kabiru gombe biography of william
Kabiru Gombe
Kabir Muhammad Haruna tí orúkọ gbajúgbajà rẹ̀ ń jẹ́ Kabiru Gombe jẹ́ onímọ̀ Islam àti oníwàásù. Láti December 2011[1] ni ó ti jẹ́ National Secretary General ti Jama'atu Izalatil Bid'ah wa Iqamatus Sunnah, èyí tí ó jẹ́ ẹgbẹ́ Salafiyyah tó gbòòrò jù lọ ní Nàìjíríà[2][3]
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Muhammad Kabir Haruna bẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i ọmọ-ẹgbé JIBWIS tí àwọn Hausa ń pè ní "Ƴan Agaji" lásìkò tó jẹ́ ọ̀dọ́; lẹ́yìn náà ni ó lọ sí Saudi Arabia láti lọ tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ ìmọ́ ẹ̀sìn Islam àti Kùránì.
Muhammad Kabir Haruna ti jé Secretary General ti ẹgbẹ́ Izala láti December 2011.[4] Ó máa ń ṣe ọdún Ramadan Tafsir, bẹ́ẹ̀ sì ni ó máa ń lọ sí oríṣiríṣi Da'wah káàkiri Nigeria àti àwọn ìlú mìíràn bí i Niger, Cameroun, Chad, Ghana, àti United Kingdom.[5][6][7][8][9][10][11][12] Muhammad Kabir Haruna máa ń ṣe ìjìnlẹ̀ ìwásù lórí ọ̀rọ̀ àwọn o